Skip to main content
Eiye Akalamagbo
ONMO TODAJU
 iye akala merindilogun, akara elepo merindilogun aoko gbongbo re sinu koko tutun aotu oyin igan le Lori dada aowafi odidi atare meji si aodepa aogbe kale fun ojo meje Leyina aojopo aofifo eko elewe mu larolaro pelu ohunyi:- bi oku Baku laye Akala amagbede ode orun akigbe oyin pamo ki era mamobe gbogbo nkan tabafe sele ni kinmamo

Comments

Popular posts from this blog

Ogun owo (respect) todaju..... Aotoju orogbo nla kan aowa pani pansa aowo inu re danu aowa fi owo eyo kansi aowa de pada aokoni bere lowu dudu ati fufun aomafisi ara jade Orogbo. 
EBE IMULE ASINA TODAJU ISENALO BAYI: Aotoju obi pupa oloju merin kan ao sun ninu ina tio jona daada obi ifin bakana oloju merin aobo lomi gbigbona tio jina Daada aoyo aowa ko sinu ape pelu odidi eiye adan kan ati atare odidi kan jijo papo aolo kuna daada ao ro sinu igo fufun kan tabi ato. LILORE: lilo asiri yi pinsi ona meji lilo akoko, Aotoju awo sobi kekere kan pelu epo pupa ti abafe sun lale aofi eyin tilekun pa aoba ebu yi die sinu awo sobi yi aofi epo si ao se adua ebe lowo awon agba ati itusile si pelu aniyan itusile aowa la aolo sun aosigbodo jade sita moo lilo keji.. Tobadi laro kutu aotun fehin tilekuna ofi ebu naa foko Tutu mu pelu adua ati aniyan ki ona owo osin lonakona aotun daniyan sugbon aniyan eleyi yato siti akoko aniyan itusile niti akoko aniyan ore owo ati ola ni aose nibi ekeji yii bi abawamu tan aosilekun sole ao joko bi iseju mewa ki a toma jade lo wallahi wallahi asiri todaju enibarise nii onabasin nii oro badi ayo
ORUKA ONISE MERIN, ONSISE OWO RESPECT, ISORA,IWOSAN, ATI MARAN  ISENALO BAYI... ojo ti adiye ba bere sini ye eyin ao ko iye oruka tio ba wuwa si ibiti on ye si ojo ti adiye na ba pa omo ao mu eyokan ninu awon omo adiye na ao fa orire tu ao fi eje re ra oruka yi aosa oruka na si orun tio gbe     lilore.. Aofi si owo aofi ahon kan fun mayehun sugbon fun iwosan aokan fi oruka sowo ni aosifi oruka na kan ibiti oban dun enina boya inu rirun fun apere aokan fi owo na le enina ninu ni arin ti oruka wa na laofile sugbon fun owo, isora ati asegbe lopin igbati ti obawa lowo wa gbogbo ise wonyen nio mase.