EBE IMULE ASINA TODAJU ISENALO BAYI: Aotoju obi pupa oloju merin kan ao sun ninu ina tio jona daada obi ifin bakana oloju merin aobo lomi gbigbona tio jina Daada aoyo aowa ko sinu ape pelu odidi eiye adan kan ati atare odidi kan jijo papo aolo kuna daada ao ro sinu igo fufun kan tabi ato. LILORE: lilo asiri yi pinsi ona meji lilo akoko, Aotoju awo sobi kekere kan pelu epo pupa ti abafe sun lale aofi eyin tilekun pa aoba ebu yi die sinu awo sobi yi aofi epo si ao se adua ebe lowo awon agba ati itusile si pelu aniyan itusile aowa la aolo sun aosigbodo jade sita moo lilo keji.. Tobadi laro kutu aotun fehin tilekuna ofi ebu naa foko Tutu mu pelu adua ati aniyan ki ona owo osin lonakona aotun daniyan sugbon aniyan eleyi yato siti akoko aniyan itusile niti akoko aniyan ore owo ati ola ni aose nibi ekeji yii bi abawamu tan aosilekun sole ao joko bi iseju mewa ki a toma jade lo wallahi wallahi asiri todaju enibarise nii onabasin nii oro badi ayo
Comments
Post a Comment