ORUKA ONISE MERIN, ONSISE OWO RESPECT, ISORA,IWOSAN, ATI MARAN
ISENALO BAYI... ojo
ti adiye ba bere sini ye eyin ao
ko iye oruka tio ba
wuwa si ibiti on ye si ojo ti adiye na ba pa
omo ao mu eyokan ninu awon
omo adiye na ao fa orire tu
ao fi eje re ra oruka yi aosa
oruka na si orun tio gbe
lilore.. Aofi si owo aofi ahon kan fun mayehun sugbon fun iwosan aokan fi oruka sowo ni aosifi oruka na kan ibiti oban dun enina boya inu rirun fun apere aokan fi owo na le enina ninu ni arin ti oruka wa na laofile sugbon fun owo, isora ati asegbe lopin igbati ti obawa lowo wa gbogbo ise wonyen nio mase.
Adupe pupo
ReplyDelete