Skip to main content
EBE IMULE
ASINA TODAJU
ISENALO BAYI: Aotoju obi pupa oloju merin
kan ao sun ninu ina
tio jona daada obi ifin bakana oloju
merin aobo lomi gbigbona tio jina Daada
aoyo aowa ko sinu ape pelu odidi eiye adan kan ati atare odidi kan jijo papo aolo kuna daada ao ro sinu igo fufun kan tabi ato.

LILORE: lilo asiri yi pinsi ona meji
lilo akoko, Aotoju awo sobi kekere kan pelu
epo pupa ti abafe sun lale aofi eyin tilekun pa aoba ebu yi die sinu awo sobi yi aofi epo si ao se adua ebe lowo awon agba ati
itusile si pelu aniyan itusile aowa la aolo
sun aosigbodo jade sita moo
lilo keji.. Tobadi laro kutu aotun fehin tilekuna ofi ebu naa foko Tutu mu pelu
adua ati aniyan ki ona owo osin
lonakona aotun daniyan sugbon aniyan eleyi yato siti akoko aniyan itusile niti akoko aniyan ore owo ati ola ni aose nibi ekeji yii bi abawamu tan aosilekun sole ao joko bi iseju mewa ki a toma jade lo
wallahi wallahi asiri todaju enibarise nii
onabasin nii oro badi ayo

Comments

Popular posts from this blog

Ogun owo (respect) todaju..... Aotoju orogbo nla kan aowa pani pansa aowo inu re danu aowa fi owo eyo kansi aowa de pada aokoni bere lowu dudu ati fufun aomafisi ara jade Orogbo. 
ORUKA ONISE MERIN, ONSISE OWO RESPECT, ISORA,IWOSAN, ATI MARAN  ISENALO BAYI... ojo ti adiye ba bere sini ye eyin ao ko iye oruka tio ba wuwa si ibiti on ye si ojo ti adiye na ba pa omo ao mu eyokan ninu awon omo adiye na ao fa orire tu ao fi eje re ra oruka yi aosa oruka na si orun tio gbe     lilore.. Aofi si owo aofi ahon kan fun mayehun sugbon fun iwosan aokan fi oruka sowo ni aosifi oruka na kan ibiti oban dun enina boya inu rirun fun apere aokan fi owo na le enina ninu ni arin ti oruka wa na laofile sugbon fun owo, isora ati asegbe lopin igbati ti obawa lowo wa gbogbo ise wonyen nio mase.