ORUKA ONISE MERIN, ONSISE OWO RESPECT, ISORA,IWOSAN, ATI MARAN ISENALO BAYI... ojo ti adiye ba bere sini ye eyin ao ko iye oruka tio ba wuwa si ibiti on ye si ojo ti adiye na ba pa omo ao mu eyokan ninu awon omo adiye na ao fa orire tu ao fi eje re ra oruka yi aosa oruka na si orun tio gbe lilore.. Aofi si owo aofi ahon kan fun mayehun sugbon fun iwosan aokan fi oruka sowo ni aosifi oruka na kan ibiti oban dun enina boya inu rirun fun apere aokan fi owo na le enina ninu ni arin ti oruka wa na laofile sugbon fun owo, isora ati asegbe lopin igbati ti obawa lowo wa gbogbo ise wonyen nio mase.
Eiye Akalamagbo ONMO TODAJU iye akala merindilogun, akara elepo merindilogun aoko gbongbo re sinu koko tutun aotu oyin igan le Lori dada aowafi odidi atare meji si aodepa aogbe kale fun ojo meje Leyina aojopo aofifo eko elewe mu larolaro pelu ohunyi:- bi oku Baku laye Akala amagbede ode orun akigbe oyin pamo ki era mamobe gbogbo nkan tabafe sele ni kinmamo